Skip to content

E Wo Nnkan Ti O Bi Fidio Tuntun Ti Olorin FALZ Se Jade Nipa Orile Ede NIGERIA

E Wo Nnkan Ti O Bi Fidio Tuntun Ti Olorin FALZ Se Jade Nipa Orile Ede NIGERIA

Nje E ti wo fidio orin FALZ The Bahdguy ti o ti ko orin kan ti o pe akole re ni “This is Nigeria” eyi ti o je afiwe orin omo ilu okere kan ti won pe oruko re ni “Childish Gambino”, o ti sina fun awon eniyan lati fi ehonu won han nipa awon nnkan ti o n sele ni Nigeria.

Awon eniyan miran ti fi eebu ranse si ogbeni Falz nitori wipe won woye wipe ko fenuba awon nnkan kookan ti o n sele ni Orile ede Nigeria. Beeni awon miran so wipe inu awon n dun wipe omo Nigeria kan le ko orin lori awon idamu ti a n f’oju ba ni Orile ede Nigeria.

Lati fi idi ati itumo orin naa mule:

Gege bi nnkan ti o so, o wipe oun ko orin naa lati fi mu ohun buruku ti o n sele ni Orile ede yii; o wipe Nnkan pataki ni ki awon olorin ati awon osere maa soro nipa nnkan ti o n sele lati fi pe ijoba si akiyesi.

E wo fidi naa nisale yii: