Skip to content

FIDIO OLAMIDE WO NI 1M VIEWS LORI YOUTUBE LAARIN OJO MEFA

Olamide baddoo gege bi oun ati awon olofufe re se ma n pe ni olorin ti gbogbo aye n soro ni pa e lowo bayi yala ni adugbo tabi lori ero abanidore kakaakiri nitori orin re ti o se gbe jade ti akole re nje “WO”. Orin naa ti fidio se jade laipe ti ni 1million views lori ero youtube laarin ojo mefa ti won fi si ori ero na….

Lai pe yi ni iroyin kan kakaakiri wipe ajo ti n mojuto Tv ati radio gbese le orin na ati awon orin miran ti ajo naa so wipe ko ri be….E KA NIBIYI: A Ko Fagile Orin Olamide, Davido ati 9ice- Ajo NBC Lo Wi Bee