Skip to content

Fidio: Kcee – Doh Doh Doh

Olorin Five Star, Kcee ti she agbejade fidio orin re ti akole re je doh doh doh.

Orin Naa ti O je Okan lara awon Orin Awo Keta Re Ni O Gbe Aworan Re Jade Fun aye ri.

 

Fidio Naa Ni a ti Owo Unlimited LA Dari.

 

E Wo Fidio Naa