Skip to content

Femi Adebayo Setan Lati Na 25m fun Ere Return Of Jelili

Osere Nollywood ati Omo Osere agba Adebayo Salami iyen Femi Adebayo ti o n ya ise ere meji kan lowo fun odun yii ti soro siwaju si lori ere re ti o n bo lona ti o pe ni Return Of Jelili; eyi ti o je ekeji ere gbajumo re Jelili Oniso.

Femi Adebayo naa ti o so wipe oun ti setan lati darapo mo awon osere ti o n pa owo lati idi gbigbe ere lo si sinima so fun awon osere egbe re pe oun setan lati na 25m si ori ere naa….femi-adebayo-orisun