Skip to content
  • Iselu

Fayose Fa Olusola Eleka Sile Gege Bi Oluropo Fun Ipo Gomina

Gomina ipinle ekiti, Ayodele Fayose ti fi ountelu Professor Kolapo Olusola Eleka gege bi oluropo e fun eto idibo ti o ma wa ye ni ekiti. Sunshine Anifowoshe, ti o je PA si gomina Fayose lo so eleyi di mimo ni ori ero abanidore facebook e.  Professor Kolapo Olusola Eleka ni igbakeji gomina ni ipinle Ekiti bayi. Ogbeni Kolapo se se gba oye professor, leyin igba ti o je oluko ni Department of Building, ni ile iwe giga Obafemi Awolowo University,fun bi odun meta le l’ogun.  Awon ayo re ni  Alternative Building Materials Development for Housing Construction, Construction Technology and Structural Mechanics.

Dr.-KOLAPO-OLUSHOLA-orisun