Eyi Ni Iye Awọn Eniyan Ti Wọn Ti Gba Fọọmu Fun Idije Ibo Aarẹ Orile Ede Nigeria Ni 2019
Pẹlu gbogbo ohun ti o n ṣẹlẹ lori Ibo ti o n bọ ni ọdun 2019, Awọn Oloṣelu ti n gb’aradi pẹlu awọn igbesẹ t’oyatọ lati jẹ ki ohun ti wọn n fẹ fun ọdun 2019 seese.
Njẹ Tani yoo j’awe-olubori nibi eto idibo naa?. Bẹẹni ‘Tani yoo di Arẹ Orilẹ ede Nigeria?” ni awọn ibeere pataki ti o n gba gbogbo orilẹ ede Nigeria kan ni asiko yii bi a ti rii gba wipe iye oludije ogoji ni o ti gba fọọmu/tabi fi ifẹ-inu wọn han lati dije ni ọdun 2019.
Ẹgbẹ Oṣelu PDP (People’s Democratic Party) ni o ni iye oludije ju ti o n ja fun ipo ẹni ti ẹgbẹ naa yoo ran lọ dije ti won si jẹ mejila pẹlu Bukọla Saraki. Sugbon ni Ẹgbẹ Oṣelu APC, Aarẹ Mohammadu Buhari nikan ni o n dije.
Ọjọkẹrindinlogun Oṣu keji ọdun 2019 ni eto idibo naa yoo waye ti awon ẹgbẹ oṣelu kọọkan yẹ ki wọn ti mu ẹni ti yoo dije fun wọn ki ọjọ naa to pe.
Eyi ni awọn Oludije kọọkan ati ẹgbẹ ti wọn to si.
- Sen.Bukola Saraki – People Democratic Party (PDP)
- David Mark – People Democratic Party (PDP)
- Jonah David Jang – People Democratic Party (PDP)
- Attahiru Bafarawa – People Democratic Party (PDP)
- Rabiu Musa Kwankwaso – People Democratic Party (PDP)
- Ahmed Buhari- People Democratic Party (PDP)
- Funmilayo Adesanya-Davies – People Democratic Party (PDP)
- Kabiru Tanimu Turaki – People’s Democratic Party (PDP)
- Ahmed Mohammed Makarfi – People’s Democratic Party (PDP)
- Ibrahim Dankwambo – People’s Democratic Party (PDP)
- Sule Lamido – People’s Democratic Party (PDP)
- Alhaji Atiku Abubakar – People Democratic Party (PDP)
- Muhammadu Buhari – All Progressive Congress (APC)
- Kingsley Moghalu – Young Progressive Party (YPP)
- Donald Duke – Social Democratic Party (SDP)
- Fela Durotoye – Alliance for New Nigerian (ANN)
- Remi Sonaiya – Kowa Party
- Thomas-Wilson Ikubese – Alliance for New Nigeria (ANN)
- Omoyele Sowore – African Action Congress (AAC)
- Enyinnaya Nnaemeka Nwosu – Abundant Nigeria Renewal Party (ANRP)
- Adesanya Fegbenro-Bryon
- Charles Udeogaranya – – All Progressive Congress (APC)
- Mathias Tsado – Action Democratic Party (ADP)
- Eniola Ojajuni – Undecided
- Olu James Omosule – Undecided
- Tope Fasua- Anrp – Abundant Nigeria Renewal Party (ANRP)
- Elishama Rosemary Ideh – Alliance For New Nigeria (ANN)
- Usman Ibrahim Alhaji – National Rescue Movement (NRM)
- Datti Baba Ahmed – All Nigeria People’s Party (ANPP)
- Adamu Garba – All Progressive Congress (APC)
- Oluwaseyitan Lawrence Aletile – Undecided
- Omike Chikeluba Lewis – Undecided
- Ibrahim Ladaja – Undecided
- Omololu Omotosho – Undecided
- Fidelis Akhalomen Lawrence Ekoh – Youth Democratic Party (YDP)
- Ibrahim Shekarau – All Progressive Congress (APC)
- Professor Iyorwuese Hagher – Social Democratic Party (SDP)
- Chike Ukaegbu – Advanced Allied Party (AAP)
- Alhaji Ibrahim Eyitayo Dan Musa – Social Democratic Party (SDP)
- Gbenga Olawepo – Alliance For New Nigeria (ANN)
- Mr Festus Obeghe – National Conscience Party(NCP)
- Dr Yunusa Tanko – National Conscience Party (NCP)
- Mrs Eunice Atuejide – National Interest Party (NIP)