Skip to content

Eyi Ni Idi Ti Ajo JAMB Ti Sun Tita Iwe Iforukosile Siwaju

Eyi Ni Idi Ti Ajo JAMB Ti Sun Tita Iwe Iforukosile Siwaju

Ajo Jamb ti o n bojuto gbigbaniwole si ile iwe eko giga agba Yunifasti ti a n pe ni JAMB ti kede wipe oun ti sun fiforuko sile awon akeko ti o fe wole si ile-iwe eko giga ni odun 2018 siwaju nitori idi kan ati omiran; eyi ti o ye kii o bere ni Ojoru Osu Beelu, Odun 2017.

Eyi di mimo lati owo agbenuso fun JAMB, Ogbeni Fabian Benjamin. O wipe isunsiwaju iforuko sile naa jade leyin igba ti won eni ti o ye ko te iwe pelebe jade fun awon ekeko ti o ba forkuko sile ko pada jade leyin idaniloju November 7th ti won so wipe yoo jade tele.

Toyosi gba awon obirin ni amoran lori awon okunrin

Gege bi nnkan ti o so ni exe geesi;

“As at close of work today, the publisher had not provided the 1.8 million copies required and this development painfully forced to the Board to shift the date from Wednesday 22nd November, 2017 to a date to be announced soon. ”

Ajo Jamb so wipe Inu awon ko dun rara fun wahala ti awon ko baa fa lori idaduro eto iforuko sile naa. O tesiwaju wipe awon yoo sise takuntakun lati lati mu Ojo tuntun fun iforukosile naa,

Awa naa n duro de Ojo tuntun ti won fe mu ki a le baa fun yin lesi.