Skip to content

EWO ITAN BI WON SE JU ANOBI IBRAHIM SI INU INA

Anobi Ibrahim (peace be upon him) je baba gbogbo awon anobi olorun. Ni igba kan ninu igbese aye Anobi Ibrahim¬†(peace be upon him) awon ara ilu ti o n waasu oro olorun fun won pete pemo lati ju sinu ina ki Allah (SWT) to gba sile… Ki lo sele gan gan? Kini Anobi Ibrahim se ti won fe fi ju si inu ina?

E TUN LE KA: Bi A Se Le Gba Lada Nipa Riran Eniyan Lo Hajj