Skip to content

Ewo Akara Oyinbo Nla Ti Jay Z Ra Fun Ojo Ibi Beyonce

Ajoyo Ojo Ibi Odun Mefa Le L’Ogbon (36th) ti olorin Beyonce ni oko re Jay z se ni ona ara. Jay z ri wipe gbogbo oju lo wa lara beyonce lori itage tie to Made In  America festival ti won se ni Philadelphia, o tun na owo iyebiye ni dollar lati se akara oyinbo to gbafe fun. Awon osise ti o wan i ibi ti won ti se akara oyinbo naa so wipe eyan kan ti o so oruko re so wipe ki awon se akara oyinbo naa ni ose kan ki ojo ibi naa to waye.

“Last week, a call came into Philadelphia’s Cake Life Bake Shop requesting some cakes and cookies for New York clientele who were coming down for the Made In America festival over the weekend,” a source revealed to Page Six.”The caller asked for various items and then specifically black-and-yellow-coloured items, including a black and yellow geode-themed cake.”

jayz-beyonce-birthday-cake-orisunbeyonce-jayz-birthday-cake-orisun

Akara Oyinbo naa ma to bi $3,500 ti won sit un fi akara oyinbo kekere kan ti o ni oyin, lavender ati goat cheese ninu tii legbe.