Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade

Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade

NFVCB je ajo ti o wa ni idi ki won ma ri wipe gbogbo orin ati sinima agbelewo pe oju osunwon fun awon agbalagba ati omode ti won ma wo. Opolopo igba si ni awon eniyan ti pe ajo NFVCB le jo nipa oniru ere ati orin ti o wa ni ita bayi ti ko see wo fun omode ti o si lodi si asa ati ise wa….

Oludari ajo NFVCB ni alejo arabirin Feyikemi lori eto wa Eto Baba Eto ni bi ti won ti soro nipa nkan ti o fa ti ajo NFVCB fi ma n gbese le awon orin ati sinima leyin ti won ba ti jade…

E TUN LE WO:Idi Ti Ijoba Se Da Ajo National Films & Video Censors Board (NFVSB)

E wo ni bi yii>>>

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here