Idi Ti Ijoba Se Da Ajo National Films & Video Censors Board (NFVSB)

Idi Ti Ijoba Se Da Ajo National Films & Video Censors Board (NFVSB)

Ajo National Films & Video Censors Board (NFVSB) lo wa ni idi ki won ri daju wipe gbogbo nkan ti o wa ni ori amumaworan yala eto, orin,sinima tabi ipolowo ba ilana ijoba ati asa ati ise orile ede wa mu….Opolopo ni o mo idi ti ijoba fi da ajo naa sile, eyi ni atokun wa Feyikemi ati alejo won ti o je alese ati oludari NFVSB yannana lori ETO BABA ETO…

E TUN LE WO:Aisha Buhari Soro Lori Aisan Ti O N Se Mohammadu Buhari

 

E wo ni bi yii>>>>

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here