IDI TI AWON OKUNRIN SE N YAN ALE (CHEAT)

IDI TI AWON OKUNRIN SE N YAN ALE (CHEAT)

Cheating ni okan lara awon idi ti ibase laarin okunrin ati obirin, loko laya, omo ati obi pelu ore s’ore. Opo obirin ati iyawo ile paapa julo ni aye yii ni won ti ma n kominu pe oko won ma n yan ale ni ta, Opo igba ni ati gbo itan nipa bi awon okunrin se ma n yan ale pelu awon omo kekeeke tabi agbalagban gan nigbami, sugbon ibeere nla ti o ma n tele ni gbogbo igba ni Kilode ti awon okunrin sse n ya le ( Why are men cheating? or Why do men cheat?)

Eyi ni oro ti a gbe yewo lori eto baba eto pelu Lara Olubo ati awon lokolaya ti won je alejo re….

 

E TUN LE WO:

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here