Ewon Egbere Ni Fun Ara ati Ore Eni To N Se Piracy-NFVCB

    Ewon Egbere Ni Fun Ara ati Ore Eni To N Se Piracy-NFVCB

    Piracy je nkan ti o n ba inu awon ti o wa ni Entertainment Industry je latari pe awon eni ibi won yi o je ki won jere ise owo won. Oga agba Ajo NFVCB ti o je alejo wa lori Eto baba Eto so wipe ewon ni eni ti o ba n se piracy ati gbogbo ebi re yoo lo. Nnkan eyokan ti alejo wa so koni eyi. O so nnkan miran ti eti yin yoo fe gbo….

    E TUN LE WO: Idi Ti NFVCB Se N Gbese Le Orin Ati Sinima Leyin Ti Won Ba Jade

    E wo ba yii>>>>

    Leave a Reply