#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)?

ATABATUBU-ABERE_ORIN-ORISUN-TV-ORISUN TELEVISION

#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)?

#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)?

Lọsọọsẹ ni Abẹrẹ orin gẹgẹ bi awọn ololufẹ Atabatubu ṣe maa n pee maa n fi orin aladun da awọn ti o n wo amohunmaworan ileeṣẹ Orisun l’araya sugbọn ti ọsẹ yii n’ẹgba ! bẹẹni o si tun n dani lọrun.

Ko yẹ ki a sọrọ ju nitori pe Yoruba bọ, wọn wipe; “Itọwo ni adun ọbẹ”

Ẹ wo fidio naa ki ẹ si gbadun awọn aṣayan orin ti Atabatubu kọ.

1 ọrọìwòye

Subscribe To Our Youtube

FI KAN ESI

Please enter your comment!
Please enter your name here