Ese Mi Koni Ye Titi Maa Fi Da Ogo Ilu Nigeria Pada
Are Muhammadu Buhari ti pinnu lati mase ye ese titi yoo fi da ogo Ilu Nigeria pada.
Buhari so eyi di mimo ni ilu kano nibi apeje kan ti Ijoba Kano gbe kale; o si fikun-un wipe oun yoo tesiwaju lati maa sa ipa toun lati fi gbe orile ede yii de ibi giga.
Ninu oro re ni ede geesi o wipe;
“I will continue to do my best because my problem is Nigeria. Nigeria is my target and I will remain focused to move the country forward,” Koje bi ohun ti o so.
O tesiwaju wipe, Ijoba oun yoo fi eto eko siwaju lati fi ran awon odo lowo lati jeki awon naa le dasi oun ti o je itesiwaju fun ilu Nigeria. O wipe;
“If you educate people, you empower them. So we have to make sacrifice to prepare the youth for the future,” Buhari said.
Inu re dun gidi gidi gaan ni nitori bi won ti gbaa towo-tese ati bi won se yo moo ni’gbati o wo inu olu-ilu naa.
O wipe;
“I am overwhelmed by the massive turnout of people who left what they were doing to welcome me. This should be a clear message to the opposition.”
“The support has been consistent, so I don’t have words to express my appreciation to the people of Kano state.”
O ki Gomina Ipinle naa Ogbeni Abdullahi Ganduje fun ise takun-takunlati fi mu igbe aye awon eniyan rorun ni ilu naa pelu awon ise ribi-ribi ti o ti se ti o kan ilu naa gbongbon.
O yin Gomina naa, o fi eni rere se apejuwe re. O ni Ganduje je eni ti o ba awon oloselu t’oku sise paapajulo awon ti o n soju Ipinle naa ni Ile igbimo asofin ti ilu naa ati apapo.
Gomina naa so wipe; lara ipa ti oun ti ko lati dawo airise duro, ijoba ti gbe ise ti o to iye owo Billionu meji Naira fun kiko awon ibi ti awon odo yoo ti maa kose. O fikun wipe, ibi’se naa ko ni pe pari ni kiko.