E Wo Nnkan Ti Ero AyarabiAsa Google Se Si Awon Orin Davido
Ero ayarabiAsa Google ti ri akitiyan Davido ni odun 2017 yii ati ibi ti o ti de ninu orin kiko ati awon ami eye miran ti o ti gba. Leyin ti won ti se ayewo awon orin ti awon eniyan n bere fun lori Google, won ri bii orin meta lati enu akorin naa.
Oun nikan ko ni won gbe ise takun-takun re yo bi ko se Orin Wo lati enu Olamide pelu One Corner lati enu Patapaa.
E wo nnkan ti Are DMW so leyin ti won gbe atejade naa sita.