Skip to content

Ibosi O..Eniyan Merin Ni Boko Haram Tun Ti Pa O

Ibosi O..Eniyan Merin Ni Boko Haram Tun Ti Pa O

Ki olorun gba wa ooo..Eniyan merin ni a gbo wipe Awon iko omo Boko Haram ti yinbon pa leyin ti won dena de won ni oju-ona. Awon Ajo ti o n mojuto oro ounje ni agbaye iyen (World Food Programme- WFP) ti o je oluranlowo fun United Nations n koja lo ni ilu Borno lojo abamet ti o koja DEC 16th Odun 2017.

Awon odaran naa dawo bo okan lara awon agbase se fun WFP ti o n gbe ounje lo fun awon alaini ti o wa ni IDP Camp ti ilu kereje kan ti a n pe ni Ngala labe ijoba-ibile Gamboru-Ngala local government. Bi o ti le je wipe awon omo-ogun tele won, awon merin ninu won ni ibon ba.

Gege bi oro ti a ri gbo lati enu agbenuso fun Ajo naa iyen Adedeji Ademigbuji, O wipe awon meji ninu awon ti o ku je Direba oko -ounje naa pelu igbakeji oun.

Ni Ede geesi, o wipe;

“WFP can confirm that a convoy escorted by the Nigerian military including WFP hired trucks was the subject of an attack by armed groups 35km southwest of Ngala in Borno State on Saturday (16 December).

“Four people, including the driver of a WFP-hired truck and a driver’s assistant, were killed in the incident. WFP extends its condolences to the bereaved families.

“WFP is working with the authorities to determine the whereabouts of the trucks.”