Skip to content

Ah O Se O! Eniyan Meji Tun Ti Ku Ni Ilu ABUJA Lori Aisan LASSA

Ah O Se O! Eniyan Meji Tun Ti Ku Ni Ilu ABUJA Lori Aisan LASSA

Ilu Abuja gba alejo oran lana ode oni bi aisan nla ibi ti awon ekute maa n fa; iyen LASSAA fever kolu awon kan laarin ilu naa.

Gege bi awon ejo kan The Federal Capital Territory Administration (FCTA) se so, awon meta ni o ni arun Lassa ni bi osu meta seyin ti meji si fo sanle ku lana.

Ogbeni Humphrey Okoroukwu, ti o je oludari fun Eto Ilera ati igbe-aye awon eniyan ni ipinle FCT ti a mo si Abuja ni o jabo fun wa ni ilu Abuja lori isele naa.

Okonkwo so wipe awon n fura si bii mejidinlogoji isele sugbon bii meta nikan ni awon ba pade ti meji si ti je oluwa ni’pe.

O wipe; Iroyin ti gbogbo aye gbo nipa Lassa ni osu March ti o koja je iroyin iku eni kan ti o kan abuku aisan naa.

Laisi ifaseyin, Dokita ati oludari FCTA (Federal Capital Territory Administration) so wipe awon agbegbe ti awon fura si naa wa ni abe amojuto awon; beeni awon ti awon fi s’abe abo fun igba die lati fi se ayewo lori won ti pada lo si ile nitori wipe ‘Eni ori yo, o di’le”

Lassa-Fever-Abuja-sickness-disease-nysc-lassa-fever-awareness-campaign_0