Bi orisirisi eniyan se n dahun si oro ipinya laarin ooni ife ati iyawo e teleri , opo omo Nigeria loti fi ehonu won han lori oro yi. Okan laarin awon ti o n fi ohonu won han ni adaniloko ati baba ifa yomi elebuibon, ti o fi han pe okunrin kokunrin ti o b aba iyawo ooni ni ajosepo yoo ku iku oro.
Gegebi Elebuibon ti so, o ni oun to wa leyin ipinya ti o waye laarin ooni ti ile ife ati iyawo re yooo leyin ti iyawo ooni yi ba ko lati se awon awemo Kankan gegebi asa Yoruba. Elebuibon ni ‘The queen will be asked to consult Ifa and Ifa will give directions on how she will make the necessary atonement for her cleansing,’.
E TUN LE KA: Emi Ati Ooni Ko Fe Ara Wa Mo – Olori Wuraola
Baba Elebuibon tun so wipe ‘In Yoruba tradition, a woman who has been married to a king cannot lay with any other man even if the marriage breaks up. But when the right atonements have been made, there won’t be any problem. If she doesn’t make the necessary atonement for cleansing, the man she marries will die a premature death or he will be struck with an unknown illness. Even after the cleansing exercise, any marriage which she goes into must not be elaborate. They should go far away and avoid any flamboyant wedding,’.