Agbaboolu fun Nigeria, Emmanuel Emenike ati iyawo re ti o je beauty queen teleri ti ki omo tuntun obirin kaabo si aarin won pelu aworan oun ati iyawo re ti won di omo tuntun won mu.
Emenike fi iroyin ayo yi si ero abanidore instgram re lati fi so fun gbogbo eyan pe oun ti bi omo obirin. O ko wip “Blessed and highly favoured, our princess is here,”
Iroyin jade wipe awon mejeeji bi omo yi si ile iwosan kan ni London. Looto ko tis i ikede gbangba lori ojo ti won ma se iyawo sugbon awon mejeeji n pe ara won ni toko ti’yawo. Awon mejeeji bere sini ferawon ni may 2016 ti won si fi oruka igbeyawo si ara won lowo ni September 2016. Emenike ko enu igbeyawo si iheoma ni ile ounje igbalode kan ni turkey nibi ti o tin gba boolu pelu egbe agbaboolu Fenerbahce.
Agbaboolu ti o je omo ogbon odun ti ko lo si ilu Greece ni ibiti o ti n gba boolu fun Olympiacos