Emi O ji Owo Nigeria O Alison Madueke ni o so eleyi.
Asoju agbe eto epo-robi ti orile -ede Nigeria Arabinrin Alison Madueke ti doju ko ajo EFCC ti o si so wipe ohun ko ji owo Nigeria.
O ni wipe nigba ti ohun ma kuro ni ijoba ohun fi Bilonu marun ati Milionu mefa dola($5.6bn) sile ni LNG ati wipe ko si owon epo-robi ni igba ti ohun wa ni ipo na. O si tun fi enu-ate ba ajo EFCC fun esun ibaje ti won fi kan.
Arabinrin Madueke ti soro si Aare Muhammed Buhari lori eto ija lori ibaje ti o gbekale ti o si so wipe,won gbe eto na kale lati ba oruko awon omo orile-ede Nigeria kan tiwon ti yan.
Ninu oro ren Alisson wipe ija lori ibaje na ko ba je gidi kani awon ajo EFCC se ise won be ise lati di ododo ibi gbogbo oro mu ki won se ma ma lo ohun tan ba ri lori ero afefe lati fi dajo lati le ba oruko awon kan je.
Alison Madueke tun so wipe ajo EFCC ti fi afikun kun si oro ti won so nipa awon ile ati ile ti ohun ni ni Ipinle Yenagoa, Bayelsa wipe awon ebi lo ni gbogbo e. O so wipe ni ojo kesan oju November odun 2016, awon soju ajo EFCC se abewo si agbo-ile awon ni Yenagoa bi awon ti se so ti ohun si u won kakiri agbegbe na. o ni iyalenu lo je fun ohun lati ri bi won bu ate lu oruko ohun lori gbogbo iwe-irohin ati ori ero afefe pelu awon akori bi ; “AJO EFCC TI FI ILE OWO IYEBIYE MADUEKE HAN”
Ko si asiri kankan ninu ile na nitori funra mi ni mo se afinhan re ni gbangba gege ofin ti so, Ninu ate ti mo fi fi awon ohun ini mi han, Ile nla merin pere lo wa nib. Sugbon nigba ti awon ajo EFCC ma gbe tiwon jade, won ni awon la won wa ile na sita ti won si pe ile ti o to opolopo bilionu Naira, bi o ti le jepe won mo iye ti o je gangan.
O ni wipe oro ni won pa mo ohun nipa oro epo-robi ti Malubu ti o nlo bi ookan-le-ni meta bilionu dola(1.3bn) ti awon eniyan mo si OPL 245.
Siwaju si,o so wipe “ohun ko fi igbakankan da oron yi sile tabi ba eniyan ti ki se ara ajo na so oro yi”. Gegebi asoju ajo ti o n risi epo-robi, ohun ko da si oro eto isuwo Malubu yato si ajo epo-robi ti o jo da awon po.. Didasi oro na ko ju ase eto epo-robi lo.
Alison so wipe, ohun lo ni ile nla ti o je milionu lone meji-din-logun milionu dola($18M). o so wipe ohun lo ni ile ti o wa ni agbegbe Margaret Thatcher ni Asokoro, Abuja.
O ni pe ko si igba kan ti ohun ni ase si owo eto epo-robi iyen NNPC.
Lakotan, nimoro re, ” emi ko le padanu awon ohun ini ti kii se temi. Mi o mo ona ati ibi ti ajo EFCC ti ri idi ti won fi so pe emi ni mo ni awon owo ati dukia yi nitori won ko ka mo mi lowo ko do si eri kankan lati fi han pe emi ni mo ni.