PROFESSOR Sulaiman Age ti department of Chemical Engineering ni University of Ilorin ti je oye vice chancellor ile eko giga unilorin. Professor Sulaiman Age, Professor Ahmad Abdulsalam and Professor Bayo Lawal ni awon ti won yan laarin awon ogun (20) ti won dije fun ipo naa.
Abdullahi Oyekan,ti o je pro-chancellor ati chairman of council ile eko giga nan i o kede iroyin yin i ojo aje,Monday August, 28. Won so wipe ajo won gbimo lati yan ogbeni age gege ni ilana Universities Amendment Act. Ise Vice chancellor tuntun na ma bere ni October 16 ti ijoba Vice Chancellor ti o wa nibe bayi Ogbeni AbdulGaniyu Ambali ma tan ni October 15.
E TUN LE KA: Miliki Express: Iba Gbe Po Okurin Ati Obirin Ni Ile Eko Giga Fasiti
Vice Chancelloe tuntun yi je VC kewa ti ile eko giga na. Ogbeni Sulaimon Age ti je Vice Chancellor teleri fun Alhikmah University, Ilorin ti won si bi won ni 1954 ni oro, irepodun local government area of kwara. Won lo si University of Detroit ni 1980 nibi ti o gba akosegboye degree ninu Chemical Engineering ati ni University of Louisville, ni 1988 nibi ti o ti gba Ph.D ninu Chemical Engineering. Ibi ti won tin se akosegboye ni Heterogeneous Catalysis/Reaction Engineering.