Skip to content

Eemo Tun Ti Wolu Oooo..Awon Agbenipa BADOO Tun Ti Pada Wa

Eemo Tun Ti Wolu Oooo..Awon Agbenipa BADOO Tun Ti Pada Wa

Wahala tun ti be sile ni Ilu Eko oooooo. Bi won ti gbe iroyin wa si eti igbo wa wipe awon Agbenipa Baddo tun ti pada si ilu Ikorodu.

Awon idile kan ni Ilu Ibeshe ni agbagbe Ikorodu ni ilu eko naa ni Isele nlaa’bi naa ti se; bi odindi Baba, omo ati iya omo naa ni awon agbenipa naa ran lo si orun are-mabo.

Gege bii nnkan ti a ri gbo lati enu Komisona awon Olopa ti Ilu eko iyen Ogbeni Imohimi Edgal bi o ti soro nipa isele naa so wipe awon nnkan ti awon n se lori oro naa ko kere rara; pelu atileyin awon Eso-Adugbo ti won n pe ni ‘Onya bo’ pelu awon olopa ladugbo naa ti gbe iwa ibaje seyin ni ida 35% ni Ilu eko.

Osere Eniola Badmus Pari Ija Pelu Iya Omo Davido

Gege bi ohun ti a tun ri gbo, awon egbe okunkun kan ni iha PPL ni ijoba Ibile Ojo pa okunrin kan ti a o tii mo oruko re ati enikan ti o sese.

It was also gathered that another cult group struck in PPL axis of Ojo Local Government Area, killing a yet-to-be-identified man, injuring another.

A ti ranse si Oga Olopa ni ipinle naa fun ekunrere lori iroyin naa, ti o si so wipe, oun yoo kan siwa laipe.

Badoo-agbenipa-ikorodu-gang-ritualists