Skip to content

Eekan ni Hajj Lilo Je Oranyan fun gbogbo Musulumi

Hajj sise je okan ninu awon opo ti o di islam mu ati ilana fun gbogbo musulumi.. Orisirisi nkan ni o diro mo lilo si hajj lati ori aniyan, nini owo ati ti olohun ba yan pe ki onitoun lo. Yala o fe lo hajj fun ra ra e tabi o fe ran eyan lo si hajj, opolopo ilana lo diro mo gege bi ALHAJI OWO ADUA se  se alaye lori eto OJUMO IRE yii..

E TUN LE WO: Fashola Ni Ko Je Ki A Tun Ilu Eko Se O – Ambode

E wo ni bi yii>>>>