Skip to content

E WO Obinrin Ti O So Wipe Oun Se IRUN Sori Ni 40Million

E WO Obinrin Ti O So Wipe Oun Se IRUN Sori Ni 40Million

Pupo ninu awon ti o n se irun ni aye ode oni ni o n nawo lori irun won sugbon eyi se wa ni kayeefi bi Arabinrin Chika Lann ti o je omo orile ede Nigeria ti o gb’afe ninu ise-awose (Model) se so wipe oun na iye owo ti o to Ogoji milionu naira.

Ninu atejade ti a ri gbo, Chika Lann di ilumooka pelu iye owo ti o so wipe oun na lori irun re. Awon eniyan ti o wa ori ero alatagba (Social media) dahun wipe iro ni o n pa; wipe otunbante lasan ni oro naa.

Chika Lann ti jade lati so wipe iro ko ni oun npa lori isele naa..O tenu moo wipe Iye ti o je gangan ni owo awon alawo funfun ($110,000); o so wipe oun ko mu ogogoro tabi oti lile kankan nigba ti oun so iye owo irun oun.

nigerian-model-Hair-irun-chika-lann-model-40-million

O ti fidio kan ranse siwa beeni o wa ni isale nibi pelu ede geesi…O ka wipe:

“‘I wasn’t drunk during my last interview when I said my hair is 40million. I’ll say it over and over again adn I won’t be apologetic about it.”