E Wo Nnkan Ti Olopa Yii Se Ti O Fi Mu Emi Onimo Yi Lo Nilu Ekiti
Oga Olopa ni ilu Ekiti ti mu okan lara awon omo re; iyen CPL. Ayodele Famodimu ti won so wipe o yin ibon pa onimoto kan ni ojo isegun ti o koja.
Agbenuso fun aeon Olopa, iyen SP Alberto Adeyemi sofun awa oniroyin ni ilu Ado Ekiti wipe ni igba ti isele naa selle ni ilu Oye Ekiti ni won ranse si awon wipe ni oju ibi ti awon olopa ti maa n da oko duro ni won ti yinbon pa Direba naa.
Ni Ede oyinbo o wipe;
BI A SE LE FI EEDU WO ARUN ARA
“He is already facing departmental orderly room trial and when the trial is concluded, he will simply be dismissed after which he will be charged to court,” Ko je bi o ti so.
Eni ti oro naa s’oju re wipe oun n bo lati Ilu Ikara ni eyi ti ko jina si Ile Ondo ti oun si rii wipe ibon dun, oko ti o si wa ni iwaju oun si yi kuro loju popo ti awon ti o wa ninu oko naa si sese.
O So ni ede geesi wipe:
“When the driver was hit by the bullet, he lost control of the bus and it somersaulted while the passengers sustained various degrees of injury,”
Gegebii nnkan ti a ri gbo lenu Mr Mohammed Olowo, awon ti o sese ninu awon ti o wa ninu oko na ko farapa pupo, itoju ti o peye si ti n lo lara won.