Skip to content

E wo Nkan Ti OSere Adunni Ade Nse Pelu Arakunrin Yi

Adunni Ade ti o je omo Yoruba ti baba e je omo Nigeria ti iya re si je American je osere ti irawo re n gbagba soke kia kia ti o sit i ko pa ninu ere Date Gone Bad ati beebeelo. LAipe pe yin i Adunni ti o je iya omo meji yi ya aworan pelu arakunrin Bolanle Ninalowo, ti won mo si Nino ti o n da Nollywood ru lowo bayii…

Awon meji yi, se gba oye brand ambassadors fun OUD Majestic ti won n se Fragrances, Perfume gifts, Space Scenting Solutions. Awon mejeeji yi yaa aworan ray ti o gbayi yi lati polowo ise won. Adunni fi awon aworan yi si ori ero abanidore Instagram re, o si ko pe; Allow me to Introduce Ma self, My name is A to dah dunni… Proud Ambassador of @oudmajestic with my co-Ambassador @iamnino_b

 

Awon aworan naa re:

Adunni-nino-b-orisun