Skip to content

E Wo Ewure Dudu Ti Oruko ALLAH Jade Lara E

E Wo Ewure Dudu Ti Oruko ALLAH Yo Lara E

Iroyin to wa leti wipe won ri keu lara omo ewure dudu kan ni agbegbe kan ni Ipinle Nigeria yii, bi o ti le je wipe kii se akoko igba ti won ma so wipe won ri keu ti o tumo si oruko ALLAH ni awon ibi kayefi Kankan, eyi ti o sele yii pe akiyesi awon eeyan gaan….

Allah's name allegedly appears on a black goat (photos)

Allah's name allegedly appears on a black goat (photos)

Allah's name allegedly appears on a black goat (photos)

Arabirin kan ti n je Rariya, ni o kede isele yi lori erpo abanidore facebook re, nigbati o fi aworan omo ewure dudu naa ti won fi awo funfun ko keu naa si lara sori facebook re…

kayefi-orisun

Laipe yii, iroyin jade pe won arakunrin kan so wipe oun ri keu to tumo si oruko ALLLAH ni ori eran didin meji ti won opa fun ileya ni 2017…