Skip to content

E Wo Eni Ti BABANGIDA Fe Ki Gbogbo Eniyan Dibo Fun Ni Odun 2019

E Wo Eni Ti BABANGIDA Fe Ki Gbogbo Eniyan Dibo Fun Ni Odun 2019

Ogagun teleri ti o ti dari orile ede Nigeria tele-tele ti f’owo si gbigbe igba ibo fun eni kan laarin awon egbe oselu ti o wa ni orile ede Nigeria; awon eniyan ko gbaagbo sugbon o wipe eni ti oun fe niyen.

Gbogbo wa ni a mo wipe Gen. Ibrahim Babangida (rtd) je eniyan pataki ni awujo wa, pelu agbara yii ni o fi pariwo oruko alhaji Kabiru Tanimu Turaki (SAN) gege bi oludije ti o yan laayo lati dije labe asia egbe PDP ni odun t’on bo.

Babangida so wipe, awon eto ti Turaki ni fun orile-ede Nigeria je nnkan ti o to lati yi Nigeria pada. Ni igba ti o bee wo ni ipinle Niger ni ilu minna ni o so oro yii ni ede geesi;

“From your agenda, I believe you mean well for this country. I think if you are given the chance, Nigeria will witness tremendous development.”

“Your roadmap can lead Nigeria to prosperity.”