Skip to content

E Wo Bi IJEBUU Se Bo Lowo Ijamba Ina Ni Ile-Itura Ti O Sun Si

Bi IJEBU Se Bo Lowo Ijamba Ina Ni Ile-Itura Ti O Sun Si

Ogbeni Omotayo Amokade ti gbogbo aye mo si Ijebuu fi fanran kan ranse si ori ero alatagba loni ojo ru lati fi dupe lowo olorun pe o yo ninu ewu ijamba ina ti o sele ni ile-itura ti o de si.

Gege bi a ti rii gbo, ero amuletutu (AC) re ni o gba ina ti o si fe jo yara naa run ki awon eniyan to sare wole lati baa pa ina naa.

O ko sori ero Alatagba wipe:

‘just escape death now. Ko si Iku lojuwa atike lakun! Glory be to God almighty for saving my life. I will not die but to live and declare the work of God. Thank you Jesus’.

E wo fidio naa Loke patapata…