Skip to content

E wo Bi Femi Adebayo Se Ki Iyawo Re Ku Ojo Ibi

Osere Femi Adebayo ti bo si ori ero abanidore Instagram lati ki iyawo re Aduke ku Ojo Ibi. Ninu atejise naa femi adebayo ki iyawo re ku aduroti, osi so wipe oun nikan ni oun n wo loju, o ni;

Femi-adebayo-orisun    Femi-adebayo-wife-orisun

Femi-adebayo-orisun

Femi Adebayo fe iyawo re Omotayo Sanusi, leyin odun mejo 8yrs ti iyawo re akoko khadijat ko sile lati fe okunrin omiran.