Skip to content

E WO BI AWON OMO ILUMOOKA SE MURA LO ILE-IWE FUN CULTURAL DAY

Awon omo ilumooka wa ni Nigeria jade lo si ile iwe won loni ni eya aso asa (traditional attire) won lati se ajoyo odun asa (Cultural day) ati Nigeria’s independence bi ilu Nigeria se ma pe odun Meta Din L’ogota ni ojo isinmi Sunday October 1st,2017.
Gbogbo won ro dede ninu awon aso asa won;

 

  1. Monalisa Chinda’s Daughter:

 

2. Bovi’s Children

 

3. Tonto Dikeh’s Son

 

4. Mercy Johnson’s Children

5. Adaeze Yobo’s Sons

6. Alibaba’s Daughter

7. AY’s Daughter

8. Anna Ebiere’s Daughter

9. Content Creator, Biodun Stephens’ Daughters

10. Tolu ijogun’s Daughter