Skip to content

E WO ARAKUNRIN TO N RAP NI EDE IJESHA; So See Daadaa?

Rap je eya orin ti o ti gba ode kan lati aye baye ti awon eeyan si n je igbadun re. opo olorin lo je wipe rap ni won n ko ti won si je ilu mooka, opo olorin si wa ti awon naa nko Rap ti won si fe blow…. Awon olorin bii Olamide, Phyno, Reminisce, Zoro ati beebeelo ni won n ko rap ni ede yoruba ati igbo….

Arakunrin ti o je alejo wa lori eto ojumo ire pelu Olori n rap pelu ede ijesha,

E wo fidio yii, ke je ki a mo boya o Rap daadaa:

E TUN LE KA: Idi Ti Won Fi N Ba Osere Obirin Sun Ni Movie Location

E TUN LE WO: