Skip to content

E wo Alex Iwobi Ninu Aworan Egbe Agbaboolu Arsenal Fun 2017/2018

Omo orile ede Nigeria ti o n gbe ni Oke okun, Alex Iwobi ti darapo mo awon iyoku egbe re ni egbe agbaboolu Arsenal  lati yaa aworan fun egbe agbaboolu naa. Gbogbo awon agbaboolu fun Arsenal pe jo po lati ya aworan fun odun 2017/2018 season ni ibi ti won ti n daraya ni London Colney leyin ti Transfer Window pari.

Iwobi ti o ti gab boolu fun Arsenal ni season yi pelu awon First Team Player nine aworan egbe agbaboolu naa.  Alexis Sanchez, Jack Wilshere ati Chuba Akpom wa ninu aworan naa pelu awon odo bi Reiss Nelson, Eddie Nketiah ati Joe Willock.

Alex-Iwobi-in-Arsenal-team-photo-orisun