Skip to content

E So Sinima Ti Omo Yin N Wo- Osere Hassan Goriola Si Awon Obi

Awon osere wa lolokan ojokan ma n tiraka lati ri wipe awon da wa laraya pelu bi won ti ma n se ere sinima agbelewo won. Bi won ti po jantere yi ni a ma n gbo pe gbogbo won pin si orisirisi egbe kakaakiri orile ede yi eyi ti o ma n fa ede aiyede laarin won lekan kan.

Osere sinima agbelewo, Ogbeni Hassan Goriola ti fi idi e mule pe pelu bi onikaluku se wa ninu egbe ototo ajosepo to danmaran wa ni aarin won osi tun menu ba ki awon obi maa so ohun ti awon omo won nwo lori amumaworan…

 

E TUN LE WO:Omo Odun Meta Ni Arun Warapa N Jeyo Ninu Eniyan

 

E wo bi o ti so siwaju ni bi yii>>>>