Skip to content

E Fun Awon Omo Yibo Laye Ni Odun 2019 Si Ipo Aare

2019 je Odun miran ti a o se Idibo gbogbo-gbo ni Nigeria. Bi awon eniyan se n gbaradi fun idibo naa ti awon egbe miran si n dide ti omiran n pinya, ni awon eniyan n soro nipa eni ti o le gbe Ile yi pade de ibi ire.

Aare Orile Ede yi tele ri Olusegun Obasanjo ti soro nipa nnkan ti oun ro nipa ki omo ile Igbo Je aare orile ede ni odun 2019.

IROYIN MIRAN WA NIBI: Se O ye Ki Ipo Aare Je Oye Idile Ni Ile Africa Tabi Nigeria

Aare Obasanjo so eyi di mimo ni Ana ojo Isegun 24th Osu yii nigbati o gba Aare gbogbo egbe onigbagbo ti ipinle ogun lalejo ni ile re ni Hilltop ti o wa ni Abeokuta.

 Throwing his weight behind the South-East geopolitical zone, Obasanjo reportedly said he thinks the South East should also have a go at the presidency in the next general elections.

In his words: Obasanjo said, “Irrespective of the thinking of the people ahead of 2019, I personally think that South-East should have a go at the Presidency too.