Skip to content

DINO MELAYE Ti Lo Gba Satifikeeti Re Ni ABU Zaria Ooo. E wo Iye Eniyan To Tu Jade

Sineto Ile igbimo asofin-agba, Ogbeni Sineto Dino Melaye ti o soju Ipin;e kogi labe asia egbe APC ti lo gba Iwe Eri ni Ilu Zaria ni ile iwe giga Ahmadu Bello University, Awon Aworan yii fihan bi awon ololufe Sineto Dino ti feran re to.

Melaye who was recently accused by online news medium Sahara Reporters of not graduating from the institution shared a photo of him holding his certificate, surrounding by his supporters.

E TUN LE KA IROYIN MIRAN NIBI: Won TI Tu Awon Omo Ile Eko Giga Unilag Ti Won Ti Mole Tele Sile O

Following the report, Melaye filed a lawsuit against the news portal and its publisher Omoyele Sowore. The case has been adjourned to June 5th 2017 for mention.

Some of the supporters wore T-shirts and Face caps with inscription “I am a Dinoist”.

Some of Melaye’s captions include, “What a solidarity”,  “Surprise today in Zaria”,  “Got my certificate today. Ajekun iya nio Je”,  “Zaria agog for Dino”, and “Dinoists receiving me today in ABU Zaria”.

E WO AWON AWORAN YII:

Dino-Melaye-Certificate-orisuntv

 

Dino-Melaye-Certificate-orisuntv

E TUN LE WO FIDIO YII FUN IGBADUN YIN: