Skip to content

Won Ko Gba Ki Won Da Dino Melaye Sile Ni Ilu KOGI O

Won Ko Gba Ki Won Da Dino Melaye Sile Ni Ilu KOGI O

Ile Ejo Magistrate ni ilu Lokoja ni ipinle Kogi ti fa’gi le idasile agbenuso fun Ila-oorun Kogi ni ile igbimo asofin; Ogbeni Dino Melaye. Adajo naa so wipe ki won fi sinu ewon titi won yoo fi da ejo esun ti won fi kan-an.

Leyin Osu die ti sineto naa ti n sa fun ipe lati ile-ejo, won ti wa ogbeni Melaye gunle ni ipinle Kogi loni Ojo keta osu karun lati gba idajo ti o peye.

Oloye awon Ile-ejo awon adajo ni ipinle Kogi, Ogbeni Suleiman Abdulahi ni o fi ase si wiwa ni ahamo fun ogbeni Melaye titi ojo-igbejo re ni Osu t’o nbo (11th June 2018)

Bi Iroyin yen se n lo, a o maa fi too yin leti.

E Wo Nnkan Ti Ero AyarabiAsa Google Se Si Awon Orin Davido

dino-melaye-orisun-tv