Skip to content

Didekun Iwokuwo Awon Osere, Ise NFVCB Ni -Femi Adebayo

Nollywood ti gba opo ibawi lori Iwokuwo awon osere obirin won ninu sinima agbelewo won, ti opo eyan si ti so orisirisi oro lori nkan ti won le se lati dekun iwa yi.  Osere sinima, Femi Adebayo na da si oro yi ni perewu….

Se e yin na faramo nkan ti o wi yii…

E TUN LE WO:E So Sinima Ti Omo Yin N Wo- Osere Hassan Goriola Si Awon Obi

E wo ni bi yii>>>>