D’banj ti kede ojo Agbekale awo orin e tuntun ti o pe ni “KingDonCome”. Awo na ti o ni orin mejila (12) bi emergency, turn down for what ati orin e oliver twist ma jade ni August 25,2017.
E TUN LE KA: Ti Mo Pada Ba Ra Arsenal, Maa Le Wenger Da Nu- Aliko Dangote
Awon olorin bi Phyno, Wande Coal, Harrysong wa ninu awo na ti Don Jazzy, Maleek Berry ati Shizzi pelu awon ti o produce orin ninu awo na
Awo ma je awo Eleekerin (4th solo studio album) ti D’banj. Awon awo ti tele je “No Long Thing” (2005), “RunDown Funk U Up”(2006), and “The Entertainer” (2008).