Skip to content

Davido Lo Pe Mi Lati Ko Remix Living Things-9ice

Nigbati opo eeyan gbo pe olorin 9ice ni orin igba pelu davido, inu opo eeyan dun, sugbon opo ni o mo bi won se jo se orin yii po. Ninu iforowanilenuwo kan ti 9ice se lai pe yi, o se aleye bi orin laarin oun ati davido se je yo.

Alase ati oludari AAR records, 9ice so wipe oun wan i irin ajo si ilu oba nigba ti oun gba ipe lati owo ikan ninu awon ti o n ba davido sise lati gba ase atise remix orin oun ti gbogbo aye n fe lowolowo yii living things…. “I was in U.S then and one guy from Davido’s team told me that Davido will be happy to be in the remix of my song which is “Living Things” Remix. Then I said ok and he recorded it.”

E TUN LE KA; Sultan Sokoto Kede September 1st Gege Bi Ojo Ileya

9ice so siwaju si wipe oun o feran lati maa se remix awon orin oun nitoripe oun o nilo iranlowo olorin egbe oun lati se orire…. “I don’t really love doing remix of my songs; I’m not a fan of remix. If you do remix of a song, that means you are not sure of what you sing in the original song.”