Olorin ile wa nigeria, Dammy Kran ti gba Ominira!!!
Olorin ti o ko Orin AMIN, ti bo ninu esun gbajue ti won fi kan ni june 2017 ni Miami, Florida. Ejo e wa ni court sugbon ijoba won ge ejo na sile won si fi dammy krane sile. Awon onimo ofin ijoba so wipe opo igba ti eni ti won fi esun kan ba san owo ti o je pada won ma n fi won sile… ‘The docket shows that no action was taken on all the charges and the case was closed today. Usually, charges are dropped in a case like this if the victim stops cooperating. Perhaps he paid back the companies involved.’
E TUN KA: Mi O Ki N Se Gbajue,E gbadura Fun Mi- Dammy Krane
Dammy Krane so ni opo igba pe oun o jebi esun ti won fi kan oun o pe eni ti o san owo oun lo si miami ni o jebi esun na nigbati o book flight pelu credit card ti won ji…. Pelu idagbasoke, o le je wipe ooto ni Dammy Krane n so….