Egbe agbaboolu crystal palace ti yo Adari agbaboolu won Frank De Boer ni ise leyin ojo meta din laadorin ti won fi si ise lati ma dari iko egbe agbaboolu naa.
Ni abe adari De boer, Crystal place o ti gbiyanju lati ni ayo kan (1 point) tabi ki won ni goolu eyekan (1 goal) ninu gbogbo games 4 merin ti won ti gba ni 2017/2018 Premier League season. Palace ti pinu llati yoo de boer ni ise leyin ti won padanu si egbe agbaboolu burnley, won sit i setan lati fi adari egbe agbaboolu England teleteleri Roy Hogson ropo re.