Skip to content

COMEDY SKIT: E Gbo Eyin Eniyan Tani O Go Ju?

COMEDY SKIT: E Gbo Eyin Eniyan Tani O Go Ju?

Lori comedy skit wa loni, a ri awon meji kan ti won fi han wa wipe awon go…Nje Tani O go ju?

Baba ati Omo n jade lo si ibi ayeye, Won ri owo nla loju ona ; Omo ni ki baba ma mu pe olewu, Inu baba dun wipe omo ohun gbon sugbon omo ni ogbon arekereke ti o fe da.. O mu owo sugbon o gan pa si be……

 

E TUN LE WO: Igbese To Ye Ile Iwe Aladani Lori Ifipabanilopo

 

E wo ere na lekunrere ni bi yii>>>

TA LO GO JU NINU BABA ATI OMO…..