Skip to content

CDQ (@cdqolowo) Ft. KISS DANIEL (@iamkissdaniel) – GBAYI

CDQ (@cdqolowo) Ft. KISS DANIEL (@iamkissdaniel) – GBAYI

Asiwaju agba fun Ileese NSNS ti awo orin ogbeni CDQ ti n jade ni o parapo pelu Kiss Daniel ti o sese di oga ara re naa lati gbe orin ‘Gbayi’ jade fun igbadun awon ololufe won.

Gbogbo wa ni a mo wipe ni ibi ti Kiss Daniel wa tele, won ko gbaa ni aye lati ba enikan-kan se orin po leyin odi Ileese GWorldwide.

Beyii, Orin naa ti jade si eti igbo yin.

E DANLODU RE NIBI:

E DANLODU RE NIBI