Skip to content

Buhari So Wipe Bisi Akande Lo Yo Jonathan Loye O

Buhari ti so wipe Bisi Akande lo yo Goodluck loye, O ni Oloye Bisi Akande je eni ti o maa n rin nipa ogbon ati ara awon ti o di egbe APC mu. Buhari tesiwaju lati so wipe APC yo Aare Goodluck Jonathan ni odun 2015.  Buhari fi oro yii lele nigba ti o dide lati so oro nipa e nigbati o se ojo ibi odun mejidinlogorin lana ojo Aiku.

O pe Bisi akande ni Olori agba lara awon agbaagba ti o di egbe APC mu. Gege bi aare naa ti se, O lo pelu awon ojulumoati awon miran lati ilu osun ti o je Gomina tele ri lati odun 1999-2003 ti o si ti sise gege bi igbakeji gomina ilu Oyo lati 1979-1983″. Ninu atejade kan ti agbenuso Aare so, Ogbeni Femi Adeshina ni ojo sunday so wipe “Bi okan lara awon opo ti o di awon egbe alatako mu rii wipe o je ki Buhari jawe olubori ati wipe o si bere ise ni irowo-rose.

buhari

Ni ede oyinbo, A rii ka wipe:

The statement by the presidential spokesman, Mr. Femi Adesina on Sunday further recognized Akande as a strategist. It read: “As one of the pillars of the opposition party that successfully ensured a round victory and smooth transition to unseat an incumbent president in 2015, the President believes Chief Akande’s wisdom, sacrifices, patriotism and commitment to the unity and development of Nigeria will always be remembered by posterity. “President Buhari affirms that Akande’s present role in the APC as a strong, visionary leader, a reconciling voice, strategist and stabilizer has paid up substantially in the enormous challenge of healing the ruling party, and the country. Chief Bisi Akande “The President extols the passionate and relentless efforts of the statesman in ensuring the entrenchment democracy in Nigeria, and the sustenance of the rule of law. “He prays that the almighty God will grant Chief Akande longer life, more strength and wisdom to continue serving the country he loves, and humanity.”