
Aare Orile ede Nigeria Muhammadu Buhari ko fi tara tara dahun ibeere ti a bi nipa fifa ijoba kale ti ko ba jawe olubori ni eto idibo ti o nbo ni ojo kerindinlogun osun keji.
A bere ibeere na ni eto wakati meji kan ti a pe apele re ni “The Candidate” ni Abuja ni ojo Wednesday, January 16, 2019.
#EtoBabaETO: NJẸ Ẹ WO ERE TI ATABATUBU SE LORI TẸLIFISAN LỌSẸ KEJI OṢU ỌWẸWẸ (October)?
Aare Orile-ede Naa Jeko di mimo pe pipadanu ibo naa dabi ohun ti ko see se ni.
NIgba ti oludari eto naa Kadaria Ahmed, beere fun idahun ti o damoran, Aare na dahun wipe Kii se igba akoko ti oun ma padanu eto idibo re, wipe oun padanu ni odun 2003, 2007 ati 2011.
#OrinTitun: ADEKUNLE GOLD (@adekunleGold) Ft. PHEELZ – IRE (remix)
Aare na sowipe, “Eleyi ki nse igba akoko ti emi ma padanu eto didbo, mo gbiyanju ni odun 2003, mo si wa ni ile ejo fun ogbon osun; 2007, mo wa ni ile ejo fun osu mejidinlogun;2011, mo wa ni ile ejo for osu mejo, Ti mosi gba ile ejo to ga ju lo.