Nje O Tona Fun Obinrin Lati Je Olori Ile Ni Awujo Omo Yoruba?

  Nje O Tona Fun Obinrin Lati Je Olori Ile Ni Awujo Omo Yoruba?

  Eku dede asiko yii eyin ololufe Orisun. Lori eto #Bosenlo t’oni ni a ti soro nipa ibasepo okunrin ati obirin ninu ile paapajulo eni ti o ye ki o se olori ile.

  Lara nnkan ti enikan so ni wipe O dara ki okunrin je olori nitori wipe lati inu itan wa ni a ti gbo wipe okunrin ni olorun oba koko da.

  Eyi ati awon nnkan miran ni awon Atokun wa so nipa akole oro wa t’oni. E fi ero’ngba yin ranse siwa (COMMENT) ti e ba ti wo fidio naa tan.

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here