Se O Leto Ki Oko Ati Iyawo Mo Ibi Ise Arawon?

  Se O Leto Ki Oko Ati Iyawo Mo Ibi Ise Arawon?

  Oko ati Iyawo omiran o mo ibi ti awon mejeji ti n sise, ti e ba bi won, won a ni awon o mo, ko shaa ti mu owo wa ile ni… Se nkan ti o da ni? Se o leto ki oko mo ibi ti aya re ti n sise? Se o leto ki iyawo mo ibi ti oko re ti n sise?

  Adogbaele ati Duduyemi n soro nipa ki oko ati iyawo mo ile ise ara won lori eto bosenlo, kini ero ti won lori e? kini ero ti yin lori e?

  E TUN LE WO: Bosenlo Ni Big Brother Naija Lori Ero Amohunmaworan

  E wo bi won ti so si ni biyii>>>>>

  Subscribe To Our Youtube

  FI KAN ESI

  Please enter your comment!
  Please enter your name here