Nkan Ti O Fa Overheating Ninu Moto ati atunse

    Nkan Ti O Fa Overheating Ninu Moto ati atunse

    Moto tabi oko je nkan ti o le daku ni igbakugba lai fi ami han pe ohun yoo da ise sile, eyi ti o je pe a le pe atun oko se iyen Mechanic pe ki o wa tun se. A mo ki laa se ti oko ba wa ni ori express tabi ona ti o jin si Mechanic? Opo eyan ni o mo ogbon ti won le da si oko ti o ba yonu. Lori eto Bosenlo, a o soro nipa bi a se le Overheating ninu oko ati nkan ti a le se si.

    E TUN LE WO:#Bosenlo: Nkan Ti A Le Se Ti Tyre Moto Ba Baje

    E wo ba yii>>

    Leave a Reply